-
Nọ́ńbà 6:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Kí Jèhófà mú kí ojú rẹ̀ tàn sí ọ+ lára, kó sì ṣojúure sí ọ.
-
-
Sáàmù 67:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
67 Ọlọ́run yóò ṣojú rere sí wa, yóò sì bù kún wa;
Yóò mú kí ojú rẹ̀ tàn sí wa lára+ (Sélà)
-