Sáàmù 80:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run, mú wa bọ̀ sípò;+Jẹ́ kí ojú rẹ tàn sí wa lára, kí a lè rí ìgbàlà.+ 4 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ìgbà wo lo máa bínú* sí àdúrà àwọn èèyàn rẹ dà?+
3 Ọlọ́run, mú wa bọ̀ sípò;+Jẹ́ kí ojú rẹ tàn sí wa lára, kí a lè rí ìgbàlà.+ 4 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ìgbà wo lo máa bínú* sí àdúrà àwọn èèyàn rẹ dà?+