Sáàmù 22:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+ 8 “Ó fi ara rẹ̀ lé Jèhófà lọ́wọ́. Kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí! Kí Ó gbà á là, ṣebí ó fẹ́ràn Rẹ̀ gan-an!”+
7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+ 8 “Ó fi ara rẹ̀ lé Jèhófà lọ́wọ́. Kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí! Kí Ó gbà á là, ṣebí ó fẹ́ràn Rẹ̀ gan-an!”+