Sáàmù 143:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jọ̀ọ́ Jèhófà, tètè dá mi lóhùn;+Agbára* mi ti tán.+ Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi,+Kí n má bàa dà bí àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*+
7 Jọ̀ọ́ Jèhófà, tètè dá mi lóhùn;+Agbára* mi ti tán.+ Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi,+Kí n má bàa dà bí àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*+