Sáàmù 43:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí pé ìwọ ni Ọlọ́run mi, odi ààbò mi.+ Kí nìdí tí o fi ta mí nù? Kí nìdí tí mo fi ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́ nítorí pé ọ̀tá mi ń ni mí lára?+
2 Nítorí pé ìwọ ni Ọlọ́run mi, odi ààbò mi.+ Kí nìdí tí o fi ta mí nù? Kí nìdí tí mo fi ń rìn kiri nínú ìbànújẹ́ nítorí pé ọ̀tá mi ń ni mí lára?+