-
Sáàmù 28:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ó ti ràn mí lọ́wọ́, ọkàn mi sì ń yọ̀,
Torí náà, màá fi orin mi yìn ín.
-
-
Sáàmù 140:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, Olùgbàlà mi tó lágbára,
O dáàbò bo orí mi ní ọjọ́ ogun.+
-