ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 132:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà ti búra fún Dáfídì,

      Ó dájú pé kò ní ṣàìmú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ pé:

      “Ọ̀kan lára ọmọ* rẹ

      Ni màá gbé gorí ìtẹ́ rẹ.+

  • Ìsíkíẹ́lì 34:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+

  • Hósíà 3:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Lẹ́yìn náà, àwọn èèyàn Ísírẹ́lì máa pa dà wá, wọ́n á wá Jèhófà Ọlọ́run wọn+ àti Dáfídì ọba wọn,+ wọ́n á sì gbọ̀n jìnnìjìnnì wá sọ́dọ̀ Jèhófà àti sí oore rẹ̀ ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn.+

  • Jòhánù 7:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Ṣebí ìwé mímọ́ sọ pé látinú ọmọ Dáfídì ni Kristi ti máa wá,+ ó sì máa wá láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+ abúlé tí Dáfídì wà tẹ́lẹ̀?”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́