-
Sáàmù 104:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Tí o bá gbé ojú rẹ pa mọ́, ìdààmú á bá wọn.
Tí o bá mú ẹ̀mí wọn kúrò, wọ́n á kú, wọ́n á sì pa dà sí erùpẹ̀.+