ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 33:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ẹni tí kò jáwọ́ nínú ṣíṣe òdodo,+

      Tó ń sọ ohun tó tọ́,+

      Tó kọ àìṣòótọ́ àti èrè jìbìtì,

      Tí ọwọ́ rẹ̀ kọ àbẹ̀tẹ́lẹ̀ dípò kó gbà á,+

      Tó ń di etí rẹ̀ sí ọ̀rọ̀ ìtàjẹ̀sílẹ̀,

      Tó sì ń di ojú rẹ̀ kó má bàa rí ohun tó burú

      16 —Ó máa gbé ní àwọn ibi gíga;

      Ibi ààbò rẹ̀* máa wà níbi àwọn àpáta tó láàbò,

      Á máa rí oúnjẹ jẹ,

      Omi ò sì ní wọ́n ọn láé.”+

  • Ìṣe 10:34, 35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Ni Pétérù bá bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀, ó ní: “Ní báyìí, ó ti wá yé mi dáadáa pé Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú,+ 35 àmọ́ ní gbogbo orílẹ̀-èdè, ẹni tó bá bẹ̀rù rẹ̀, tó sì ń ṣe ohun tí ó tọ́ ni ẹni ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́