Diutarónómì 32:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’ Náhúmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀. Róòmù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ má ṣe fúnra yín gbẹ̀san, ẹ̀yin olùfẹ́, àmọ́ ẹ fàyè sílẹ̀ fún ìrunú;*+ nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san, ni Jèhófà* wí.”+
35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’
2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.
19 Ẹ má ṣe fúnra yín gbẹ̀san, ẹ̀yin olùfẹ́, àmọ́ ẹ fàyè sílẹ̀ fún ìrunú;*+ nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san, ni Jèhófà* wí.”+