Sáàmù 124:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ká ní Jèhófà ò wà pẹ̀lú wa ni+Nígbà tí àwọn èèyàn dìde láti bá wa jà,+3 Wọn ì bá ti gbé wa mì láàyè+Nígbà tí inú wọn ń ru sí wa.+ 2 Kọ́ríńtì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó gbà wá sílẹ̀ látinú irú ewu ikú tó lágbára bẹ́ẹ̀, ó sì máa gbà wá sílẹ̀, òun la gbẹ́kẹ̀ lé pé á máa gbà wá sílẹ̀ nìṣó.+
2 “Ká ní Jèhófà ò wà pẹ̀lú wa ni+Nígbà tí àwọn èèyàn dìde láti bá wa jà,+3 Wọn ì bá ti gbé wa mì láàyè+Nígbà tí inú wọn ń ru sí wa.+
10 Ó gbà wá sílẹ̀ látinú irú ewu ikú tó lágbára bẹ́ẹ̀, ó sì máa gbà wá sílẹ̀, òun la gbẹ́kẹ̀ lé pé á máa gbà wá sílẹ̀ nìṣó.+