Sáàmù 54:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Ọlọ́run ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Jèhófà wà pẹ̀lú àwọn tó ń tì mí* lẹ́yìn. Sáàmù 118:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà wà lẹ́yìn mi; mi ò ní bẹ̀rù.+ Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?+