ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 93:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 93 Jèhófà ti di Ọba!+

      Ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí aṣọ;

      Jèhófà gbé agbára wọ̀;

      Ó fi di ara rẹ̀ bí àmùrè.

      Ayé* fìdí múlẹ̀ gbọn-in;

      Kò ṣeé ṣí nípò.*

  • Sáàmù 97:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 97 Jèhófà ti di Ọba!+

      Kí inú ayé máa dùn.+

      Kí ọ̀pọ̀ erékùṣù máa yọ̀.+

  • Ìfihàn 11:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Áńgẹ́lì keje fun kàkàkí rẹ̀.+ Àwọn ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ìjọba ayé ti di Ìjọba Olúwa wa+ àti ti Kristi rẹ̀,+ ó sì máa jọba títí láé àti láéláé.”+

  • Ìfihàn 19:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Mo sì gbọ́ ohun tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an àti bí ìró omi tó pọ̀ àti bí ìró àwọn ààrá tó rinlẹ̀. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà,*+ torí Jèhófà* Ọlọ́run wa, Olódùmarè,+ ti bẹ̀rẹ̀ sí í jọba!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́