Léfítíkù 26:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Màá sì rántí májẹ̀mú tí mo bá Jékọ́bù dá+ àti májẹ̀mú tí mo bá Ísákì dá,+ màá rántí májẹ̀mú tí mo bá Ábúráhámù dá,+ màá sì rántí ilẹ̀ náà. Lúùkù 1:54, 55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 Ó ti wá ran Ísírẹ́lì ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, ó rántí àánú rẹ̀,+ 55 bó ṣe sọ fún àwọn baba ńlá wa, fún Ábúráhámù àti ọmọ* rẹ̀,+ títí láé.”
42 Màá sì rántí májẹ̀mú tí mo bá Jékọ́bù dá+ àti májẹ̀mú tí mo bá Ísákì dá,+ màá rántí májẹ̀mú tí mo bá Ábúráhámù dá,+ màá sì rántí ilẹ̀ náà.
54 Ó ti wá ran Ísírẹ́lì ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, ó rántí àánú rẹ̀,+ 55 bó ṣe sọ fún àwọn baba ńlá wa, fún Ábúráhámù àti ọmọ* rẹ̀,+ títí láé.”