ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 17:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ọlọ́run fèsì pé: “Ó dájú pé Sérà ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o sì sọ ọ́ ní Ísákì.*+ Màá sì fìdí májẹ̀mú mi tí mo bá a dá múlẹ̀, ó máa jẹ́ májẹ̀mú ayérayé fún àtọmọdọ́mọ* rẹ̀.+

  • Míkà 7:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 O máa jẹ́ olóòótọ́ sí Jékọ́bù,

      Ìfẹ́ tí o ní sí Ábúráhámù kò ní yẹ̀,

      Bí o ṣe búra fún àwọn baba ńlá wa láti ìgbà àtijọ́.+

  • Gálátíà 3:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn ìlérí náà la sọ fún Ábúráhámù àti fún ọmọ* rẹ̀.+ Kò sọ pé, “àti fún àwọn ọmọ* rẹ,” bíi pé wọ́n pọ̀. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé, “àti fún ọmọ* rẹ,” ìyẹn ẹnì kan ṣoṣo, tó jẹ́ Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́