Sáàmù 98:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó rántí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ sí ilé Ísírẹ́lì.+ Gbogbo ayé ti rí ìgbàlà* Ọlọ́run wa.+ Àìsáyà 41:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Àmọ́ ìwọ Ísírẹ́lì ni ìránṣẹ́ mi,+Ìwọ Jékọ́bù, ẹni tí mo yàn,+Ọmọ* Ábúráhámù ọ̀rẹ́ mi,+ 9 Ìwọ tí mo mú láti àwọn ìkángun ayé,+Ìwọ tí mo pè láti àwọn apá ibi tó jìnnà jù níbẹ̀. Mo sọ fún ọ pé, ‘Ìwọ ni ìránṣẹ́ mi;+Mo ti yàn ọ́; Mi ò kọ̀ ọ́.+
3 Ó rántí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ sí ilé Ísírẹ́lì.+ Gbogbo ayé ti rí ìgbàlà* Ọlọ́run wa.+
8 “Àmọ́ ìwọ Ísírẹ́lì ni ìránṣẹ́ mi,+Ìwọ Jékọ́bù, ẹni tí mo yàn,+Ọmọ* Ábúráhámù ọ̀rẹ́ mi,+ 9 Ìwọ tí mo mú láti àwọn ìkángun ayé,+Ìwọ tí mo pè láti àwọn apá ibi tó jìnnà jù níbẹ̀. Mo sọ fún ọ pé, ‘Ìwọ ni ìránṣẹ́ mi;+Mo ti yàn ọ́; Mi ò kọ̀ ọ́.+