-
Jeremáyà 33:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Bí mo ṣe fìdí májẹ̀mú mi nípa ọ̀sán àti òru múlẹ̀+ àti òfin* nípa ọ̀run àti ayé,+ 26 bẹ́ẹ̀ ni mi ò jẹ́ kọ àtọmọdọ́mọ* Jékọ́bù àti ti Dáfídì ìránṣẹ́ mi, kí n bàa lè máa mú lára ọmọ* rẹ̀ láti jẹ́ alákòóso lórí àtọmọdọ́mọ* Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù. Nítorí màá kó àwọn tó wà ní oko ẹrú lára wọn jọ,+ màá sì ṣàánú wọn.’”+
-