Sáàmù 9:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà; wo ìyà tí àwọn tó kórìíra mi fi ń jẹ mí,Ìwọ tó gbé mi dìde láti àwọn ẹnubodè ikú,+14 Kí n lè máa kéde àwọn iṣẹ́ rẹ tí ó yẹ fún ìyìn ní àwọn ẹnubodè ọmọbìnrin Síónì,+Kí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ sì lè máa mú inú mi dùn.+ Sáàmù 22:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Màá sọ orúkọ rẹ fún àwọn arákùnrin mi;+Màá sì yìn ọ́ láàárín ìjọ.+ Àìsáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+
13 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà; wo ìyà tí àwọn tó kórìíra mi fi ń jẹ mí,Ìwọ tó gbé mi dìde láti àwọn ẹnubodè ikú,+14 Kí n lè máa kéde àwọn iṣẹ́ rẹ tí ó yẹ fún ìyìn ní àwọn ẹnubodè ọmọbìnrin Síónì,+Kí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ sì lè máa mú inú mi dùn.+
11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+