Diutarónómì 33:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+ Àìsáyà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀.
26 Kò sí ẹni tó dà bí Ọlọ́run tòótọ́+ Jéṣúrúnì,+Tó ń la ọ̀run kọjá kó lè ràn ọ́ lọ́wọ́,Tó sì ń gun àwọsánmà* nínú ọlá ńlá rẹ̀.+
19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀.