ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 38:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Ta ló gbọ́n débi tó fi lè ka àwọn ìkùukùu,*

      Àbí ta ló lè da omi inú àwọn ìṣà omi ojú ọ̀run,+

  • Sáàmù 147:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ẹni tó ń fi àwọsánmà bo ojú ọ̀run,

      Ẹni tó ń pèsè òjò fún ayé,+

      Ẹni tó ń mú kí koríko hù+ lórí àwọn òkè.

  • Jeremáyà 10:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nígbà tó bá fọhùn,

      Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+

      Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+

      Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,

      Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+

  • Émọ́sì 9:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 ‘Ẹni tó ṣe àwọn àtẹ̀gùn Rẹ̀ lọ sí ọ̀run,

      Tó sì dá àwọn nǹkan sí òkè ayé;

      Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkun,

      Kí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+

      Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.’+

  • Mátíù 5:45
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 kí ẹ lè fi hàn pé ọmọ Baba yín tó wà ní ọ̀run lẹ jẹ́,+ torí ó ń mú kí oòrùn rẹ̀ ràn sórí àwọn èèyàn burúkú àtàwọn èèyàn rere, ó sì ń mú kí òjò rọ̀ sórí àwọn olódodo àti aláìṣòdodo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́