-
Diutarónómì 7:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 o ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù wọn.+ Rán ara rẹ létí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sí Fáráò àti gbogbo Íjíbítì,+ 19 àwọn ìdájọ́* tó rinlẹ̀ tí o fojú ara rẹ rí, àwọn iṣẹ́ àmì àti àwọn iṣẹ́ ìyanu+ àti ọwọ́ agbára àti apá tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ nà jáde tó fi mú ọ kúrò.+ Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa ṣe sí gbogbo àwọn tí ò ń bẹ̀rù nìyẹn.+
-