Àìsáyà 37:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Fetí sílẹ̀, Jèhófà, kí o sì gbọ́!+ La ojú rẹ, Jèhófà, kí o sì rí i!+ Kí o gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Senakérúbù fi ránṣẹ́ láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè.+
17 Fetí sílẹ̀, Jèhófà, kí o sì gbọ́!+ La ojú rẹ, Jèhófà, kí o sì rí i!+ Kí o gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Senakérúbù fi ránṣẹ́ láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè.+