Ẹ́kísódù 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wò ó! Èmi yóò dúró níwájú rẹ lórí àpáta tó wà ní Hórébù. Kí o lu àpáta náà, omi yóò jáde látinú rẹ̀, àwọn èèyàn náà á sì mu ún.”+ Mósè ṣe bẹ́ẹ̀ níṣojú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì. 1 Kọ́ríńtì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+ 1 Kọ́ríńtì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 gbogbo wọn sì mu ohun mímu tẹ̀mí+ kan náà. Torí wọ́n ti máa ń mu látinú àpáta tẹ̀mí tó ń tẹ̀ lé wọn, àpáta náà sì dúró fún* Kristi.+
6 Wò ó! Èmi yóò dúró níwájú rẹ lórí àpáta tó wà ní Hórébù. Kí o lu àpáta náà, omi yóò jáde látinú rẹ̀, àwọn èèyàn náà á sì mu ún.”+ Mósè ṣe bẹ́ẹ̀ níṣojú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì.
10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+
4 gbogbo wọn sì mu ohun mímu tẹ̀mí+ kan náà. Torí wọ́n ti máa ń mu látinú àpáta tẹ̀mí tó ń tẹ̀ lé wọn, àpáta náà sì dúró fún* Kristi.+