Sáàmù 15:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ 2 Ẹni tó ń rìn láìlẹ́bi,*+Tó ń ṣe ohun tí ó tọ́+Tó sì ń sọ òtítọ́ nínú ọkàn rẹ̀.+ Àìsáyà 64:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O ti bá àwọn tó ń fayọ̀ ṣe ohun tó tọ́ pàdé,+Àwọn tó ń rántí rẹ, tí wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ọ̀nà rẹ. Wò ó! Inú bí ọ, nígbà tí à ń ṣẹ̀ ṣáá,+Ó pẹ́ gan-an tí a fi ṣe bẹ́ẹ̀. Ṣé ó wá yẹ ká rígbàlà báyìí?
15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ 2 Ẹni tó ń rìn láìlẹ́bi,*+Tó ń ṣe ohun tí ó tọ́+Tó sì ń sọ òtítọ́ nínú ọkàn rẹ̀.+
5 O ti bá àwọn tó ń fayọ̀ ṣe ohun tó tọ́ pàdé,+Àwọn tó ń rántí rẹ, tí wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ọ̀nà rẹ. Wò ó! Inú bí ọ, nígbà tí à ń ṣẹ̀ ṣáá,+Ó pẹ́ gan-an tí a fi ṣe bẹ́ẹ̀. Ṣé ó wá yẹ ká rígbàlà báyìí?