Nọ́ńbà 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n kóra jọ láti ta ko+ Mósè àti Áárónì, wọ́n sì sọ fún wọn pé: “Ó tó gẹ́ẹ́ yín! Gbogbo àpéjọ yìí jẹ́ mímọ́,+ gbogbo wọn pátá, Jèhófà sì wà láàárín wọn.+ Kí ló dé tí ẹ fi ń gbé ara yín ga lórí ìjọ Jèhófà?”
3 Wọ́n kóra jọ láti ta ko+ Mósè àti Áárónì, wọ́n sì sọ fún wọn pé: “Ó tó gẹ́ẹ́ yín! Gbogbo àpéjọ yìí jẹ́ mímọ́,+ gbogbo wọn pátá, Jèhófà sì wà láàárín wọn.+ Kí ló dé tí ẹ fi ń gbé ara yín ga lórí ìjọ Jèhófà?”