-
Nọ́ńbà 25:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìgbà yẹn gan-an ni ọmọ Ísírẹ́lì kan wá mú obìnrin+ Mídíánì kan wá sí tòsí ibi tí àwọn èèyàn rẹ̀ wà, níṣojú Mósè àti gbogbo àpéjọ Ísírẹ́lì, nígbà tí wọ́n ń sunkún ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.
-