Sáàmù 106:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Gbà wá, Jèhófà Ọlọ́run wa,+Kí o sì kó wa jọ látinú àwọn orílẹ̀-èdè+Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ,Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+ Jeremáyà 29:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá sì jẹ́ kí ẹ rí mi,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá kó yín pa dà láti oko ẹrú, màá sì kó yín jọ láti inú gbogbo orílẹ̀-èdè àti gbogbo ibi tí mo fọ́n yín ká sí,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá sì mú yín pa dà wá sí ibi tí mo ti jẹ́ kí wọ́n kó yín lọ sí ìgbèkùn.’+
47 Gbà wá, Jèhófà Ọlọ́run wa,+Kí o sì kó wa jọ látinú àwọn orílẹ̀-èdè+Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ,Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+
14 Màá sì jẹ́ kí ẹ rí mi,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá kó yín pa dà láti oko ẹrú, màá sì kó yín jọ láti inú gbogbo orílẹ̀-èdè àti gbogbo ibi tí mo fọ́n yín ká sí,’+ ni Jèhófà wí. ‘Màá sì mú yín pa dà wá sí ibi tí mo ti jẹ́ kí wọ́n kó yín lọ sí ìgbèkùn.’+