-
Léfítíkù 7:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Tó bá mú un wá láti fi ṣe ìdúpẹ́,+ kó mú ẹbọ ìdúpẹ́ náà wá pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú tí wọ́n pò mọ́ òróró, tó sì rí bí òrùka, búrẹ́dì aláìwú pẹlẹbẹ tí wọ́n pò mọ́ òróró àti búrẹ́dì tó rí bí òrùka tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná ṣe, tí wọ́n pò dáadáa tí wọ́n sì pò mọ́ òróró.
-