ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ọfà* àwọn alágbára ọkùnrin ti ṣẹ́ sí wẹ́wẹ́,

      Ṣùgbọ́n àwọn tó ń kọsẹ̀ ni a ti fún ní agbára.+

  • 2 Sámúẹ́lì 22:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Wàá fún mi lókun láti jagun,+

      Wàá sì mú kí àwọn ọ̀tá mi ṣubú sábẹ́ mi.+

  • Àìsáyà 40:29-31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ó ń fún ẹni tó ti rẹ̀ ní agbára,

      Ó sì ń fún àwọn tí kò lókun* ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ okun.+

      30 Ó máa rẹ àwọn ọmọdékùnrin, okun wọn sì máa tán,

      Àwọn ọ̀dọ́kùnrin máa kọsẹ̀, wọ́n á sì ṣubú,

      31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà.

      Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+

      Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;

      Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́