1 Sámúẹ́lì 17:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Dáfídì ki ọwọ́ bọ inú àpò rẹ̀, ó mú òkúta kan níbẹ̀, ó sì ta á. Ó ba iwájú orí Filísínì náà, òkúta náà wọ orí rẹ̀ lọ, ó sì ṣubú ní ìdojúbolẹ̀.+ Sáàmù 44:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,+Kì í sì í ṣe apá wọn ló mú kí wọ́n ṣẹ́gun.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti apá rẹ+ àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ ló ṣe é,Nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.+ Sáàmù 44:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Agbára rẹ la ó fi lé àwọn ọ̀tá wa pa dà;+Orúkọ rẹ la ó fi tẹ àwọn tó dìde sí wa rẹ́.+
49 Dáfídì ki ọwọ́ bọ inú àpò rẹ̀, ó mú òkúta kan níbẹ̀, ó sì ta á. Ó ba iwájú orí Filísínì náà, òkúta náà wọ orí rẹ̀ lọ, ó sì ṣubú ní ìdojúbolẹ̀.+
3 Kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,+Kì í sì í ṣe apá wọn ló mú kí wọ́n ṣẹ́gun.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti apá rẹ+ àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ ló ṣe é,Nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.+