-
Sáàmù 55:12-14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Kì í ṣe elénìní ló dìde sí mi;
Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, mi ò bá sá pa mọ́ fún un.
14 Ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ni wá tẹ́lẹ̀, a sì gbádùn ọ̀rẹ́ wa;
A máa ń bá ọ̀pọ̀ èèyàn rìn lọ sí ilé Ọlọ́run.
-