Hébérù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 (torí ní tòótọ́, àwọn èèyàn wà tí wọ́n ti di àlùfáà láìsí ìbúra, àmọ́ ti ẹni yìí rí bẹ́ẹ̀ nípasẹ̀ ìbúra tí a ṣe nípa rẹ̀ látọ̀dọ̀ Ẹni tó sọ pé: “Jèhófà* ti búra, kò sì ní pèrò dà,* ó ní, ‘Ìwọ jẹ́ àlùfáà títí láé’”),+ Hébérù 7:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí àwọn èèyàn tó ní àìlera ni Òfin ń yàn ṣe àlùfáà àgbà,+ àmọ́ Ọmọ ni ọ̀rọ̀ ìbúra+ tí a ṣe lẹ́yìn Òfin yàn, ẹni tí a ti sọ di pípé+ títí láé.
21 (torí ní tòótọ́, àwọn èèyàn wà tí wọ́n ti di àlùfáà láìsí ìbúra, àmọ́ ti ẹni yìí rí bẹ́ẹ̀ nípasẹ̀ ìbúra tí a ṣe nípa rẹ̀ látọ̀dọ̀ Ẹni tó sọ pé: “Jèhófà* ti búra, kò sì ní pèrò dà,* ó ní, ‘Ìwọ jẹ́ àlùfáà títí láé’”),+
28 Torí àwọn èèyàn tó ní àìlera ni Òfin ń yàn ṣe àlùfáà àgbà,+ àmọ́ Ọmọ ni ọ̀rọ̀ ìbúra+ tí a ṣe lẹ́yìn Òfin yàn, ẹni tí a ti sọ di pípé+ títí láé.