Sáàmù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà? Òwe 3:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 O ò ní bẹ̀rù àjálù òjijì+Tàbí ìjì tó ń bọ̀ lórí àwọn ẹni burúkú.+
27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà?