Ẹ́kísódù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+ Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+ Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+