Sáàmù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí òkú kò lè sọ nípa* rẹ;Àbí, ta ló lè yìn ọ́ nínú Isà Òkú?*+ Sáàmù 71:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọlọ́run, o ti kọ́ mi láti ìgbà èwe mi wá,+Títí di báyìí, mò ń kéde àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+