Sáàmù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+ Sáàmù 19:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá. Sáàmù 119:72 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 72 Òfin tí o kéde dára fún mi,+Ó dára ju ẹgbẹẹgbẹ̀rún wúrà àti fàdákà lọ.+
8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+