Sáàmù 119:154 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 154 Gbèjà mi,* kí o sì gbà mí sílẹ̀;+Mú kí n máa wà láàyè bí o ti ṣèlérí.* Sáàmù 143:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, jọ̀wọ́ jẹ́ kí n máa wà láàyè nítorí orúkọ rẹ. Gbà mí* nínú wàhálà nítorí òdodo rẹ.+