Sáàmù 33:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó nífẹ̀ẹ́ òdodo àti ìdájọ́ òdodo.+ Ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ kún inú ayé.+ Sáàmù 104:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó ń bomi rin àwọn òkè láti àwọn yàrá òkè rẹ̀.+ Iṣẹ́ ọwọ́* rẹ ń tẹ́ ilẹ̀ ayé lọ́rùn.+