Sáàmù 65:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ò ń bójú tó ayé,O mú kí ó ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èso,* kí ilẹ̀ rẹ̀ sì lọ́ràá dáadáa.+ Omi kún inú odò Ọlọ́run;O pèsè oúnjẹ* fún wọn,+Nítorí bí o ṣe ṣètò ayé nìyẹn. Ìṣe 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 bó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò ṣàìfi ẹ̀rí irú ẹni tí òun jẹ́ hàn+ ní ti pé ó ń ṣe rere, ó ń rọ òjò fún yín láti ọ̀run, ó sì ń fún yín ní àwọn àsìkò tí irè oko ń jáde,+ ó ń fi oúnjẹ bọ́ yín, ó sì ń fi ayọ̀ kún ọkàn yín.”+
9 Ò ń bójú tó ayé,O mú kí ó ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èso,* kí ilẹ̀ rẹ̀ sì lọ́ràá dáadáa.+ Omi kún inú odò Ọlọ́run;O pèsè oúnjẹ* fún wọn,+Nítorí bí o ṣe ṣètò ayé nìyẹn.
17 bó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò ṣàìfi ẹ̀rí irú ẹni tí òun jẹ́ hàn+ ní ti pé ó ń ṣe rere, ó ń rọ òjò fún yín láti ọ̀run, ó sì ń fún yín ní àwọn àsìkò tí irè oko ń jáde,+ ó ń fi oúnjẹ bọ́ yín, ó sì ń fi ayọ̀ kún ọkàn yín.”+