Sáàmù 119:61 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 61 Okùn àwọn ẹni burúkú yí mi ká,Àmọ́ mi ò gbàgbé òfin rẹ.+ Sáàmù 119:176 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 176 Mo ti ṣìnà bí àgùntàn tó sọ nù.+ Wá ìránṣẹ́ rẹ,Nítorí mi ò gbàgbé àwọn àṣẹ rẹ.+