Sáàmù 95:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+ Lúùkù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ọkùnrin wo nínú yín, tó ní ọgọ́rùn-ún (100) àgùntàn, ló jẹ́ pé tí ọ̀kan nínú wọn bá sọ nù, kò ní fi mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (99) yòókù sílẹ̀ nínú aginjù, kó sì wá èyí tó sọ nù lọ títí ó fi máa rí i?+ 1 Pétérù 2:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí ẹ dà bí àwọn àgùntàn tó sọnù,+ àmọ́ ẹ ti wá pa dà sọ́dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn+ àti alábòójútó ọkàn* yín.
7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+ Lúùkù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ọkùnrin wo nínú yín, tó ní ọgọ́rùn-ún (100) àgùntàn, ló jẹ́ pé tí ọ̀kan nínú wọn bá sọ nù, kò ní fi mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (99) yòókù sílẹ̀ nínú aginjù, kó sì wá èyí tó sọ nù lọ títí ó fi máa rí i?+ 1 Pétérù 2:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí ẹ dà bí àwọn àgùntàn tó sọnù,+ àmọ́ ẹ ti wá pa dà sọ́dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn+ àti alábòójútó ọkàn* yín.
4 “Ọkùnrin wo nínú yín, tó ní ọgọ́rùn-ún (100) àgùntàn, ló jẹ́ pé tí ọ̀kan nínú wọn bá sọ nù, kò ní fi mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (99) yòókù sílẹ̀ nínú aginjù, kó sì wá èyí tó sọ nù lọ títí ó fi máa rí i?+
25 Torí ẹ dà bí àwọn àgùntàn tó sọnù,+ àmọ́ ẹ ti wá pa dà sọ́dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn+ àti alábòójútó ọkàn* yín.