Sáàmù 22:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ kòkòrò mùkúlú ni mí, èmi kì í ṣe èèyàn,Àwọn èèyàn ń fi mí ṣẹ̀sín,* aráyé ò sì kà mí sí.+ 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+
6 Àmọ́ kòkòrò mùkúlú ni mí, èmi kì í ṣe èèyàn,Àwọn èèyàn ń fi mí ṣẹ̀sín,* aráyé ò sì kà mí sí.+ 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+