Sáàmù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìbẹ̀rù Jèhófà+ mọ́, ó wà títí láé. Àwọn ìdájọ́ Jèhófà jẹ́ òótọ́, òdodo ni wọ́n látòkè délẹ̀.+ Jòhánù 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Sọ wọ́n di mímọ́* nípasẹ̀ òtítọ́;+ òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ.+