Àìsáyà 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+ Àìsáyà 40:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+
3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+
28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+