Sáàmù 121:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Ẹni tó ń ṣọ́ Ísírẹ́lì kì í tòògbé,Bẹ́ẹ̀ ni kì í sùn.+ Àìsáyà 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+
3 Èmi, Jèhófà ń dáàbò bò ó.+ Gbogbo ìgbà ni mò ń bomi rin ín.+ Mò ń dáàbò bò ó tọ̀sántòru,Kí ẹnikẹ́ni má bàa ṣe é léṣe.+