Sáàmù 91:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O ò ní bẹ̀rù àwọn ohun tó ń kó jìnnìjìnnì báni ní òru+Tàbí ọfà tó ń fò ní ọ̀sán+ 6 Tàbí àjàkálẹ̀ àrùn tó ń yọ́ kẹ́lẹ́ nínú òkùnkùnTàbí ìparun tó ń ṣọṣẹ́ ní ọ̀sán gangan.
5 O ò ní bẹ̀rù àwọn ohun tó ń kó jìnnìjìnnì báni ní òru+Tàbí ọfà tó ń fò ní ọ̀sán+ 6 Tàbí àjàkálẹ̀ àrùn tó ń yọ́ kẹ́lẹ́ nínú òkùnkùnTàbí ìparun tó ń ṣọṣẹ́ ní ọ̀sán gangan.