-
Àìsáyà 60:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Torí, wò ó! òkùnkùn máa bo ayé,
Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì máa bo àwọn orílẹ̀-èdè;
Àmọ́ Jèhófà máa tàn sára rẹ,
Wọ́n sì máa rí ògo rẹ̀ lára rẹ.
-