ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 49:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+

      Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+

      Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+

      Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+

  • Ìfihàn 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ebi ò ní pa wọ́n mọ́, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni oòrùn ò ní pa wọ́n, ooru èyíkéyìí tó ń jóni ò sì ní mú wọn,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́