Sáàmù 121:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Oòrùn kò ní pa ọ́ lára ní ọ̀sán,+Tàbí òṣùpá ní òru.+ Àìsáyà 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+
10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+