Àìsáyà 55:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òùngbẹ ń gbẹ,+ ẹ wá síbi omi!+ Ẹ̀yin tẹ́ ò ní owó, ẹ wá, ẹ rà, kí ẹ sì jẹ! Àní, ẹ wá, ẹ ra wáìnì àti wàrà+ lọ́fẹ̀ẹ́, láìsan owó.+ Àìsáyà 65:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa jẹun, àmọ́ ebi máa pa ẹ̀yin.+ Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa mu,+ àmọ́ òùngbẹ máa gbẹ ẹ̀yin. Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa yọ̀,+ àmọ́ ojú máa ti ẹ̀yin.+
55 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òùngbẹ ń gbẹ,+ ẹ wá síbi omi!+ Ẹ̀yin tẹ́ ò ní owó, ẹ wá, ẹ rà, kí ẹ sì jẹ! Àní, ẹ wá, ẹ ra wáìnì àti wàrà+ lọ́fẹ̀ẹ́, láìsan owó.+
13 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa jẹun, àmọ́ ebi máa pa ẹ̀yin.+ Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa mu,+ àmọ́ òùngbẹ máa gbẹ ẹ̀yin. Wò ó! Àwọn ìránṣẹ́ mi máa yọ̀,+ àmọ́ ojú máa ti ẹ̀yin.+